PDP dahun si ẹsun Oyetọla ati APC, O ni pe ki ile ẹjọ da ẹjọ naa nu. Ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party ti sọ pe ko si ootọ ninu ọrọ awọn agbẹjọro gomina Oyetoal ti APC ni Osun. Gomina Oyetola to jẹ ...
Ajọ to n mojuto ipese ounjẹ ati oogun ni Naijiria, NAFDAC, sọ pe oun ti bẹrẹ iṣẹ lori oogun coronavirus mẹrin l'orilẹ-ede Naijiria. Oludari Agba fun ajọ naa, Ọjọgbọn Mojisola Adeyeye lo sọ bẹ ẹ ninu ...